[Music] Adeyemi oluwatobi som - Oro Nla

[Music] Adeyemi oluwatobi som - Oro NlaOro nla it's an inspirational song from holyspirit.. was composed by Adeyemi oluwatobi SOM  during Som Music rehearsals after the night which was led through a dream to do the song the song was prouduced by prowhales

Lyrics

Intro-Ako ninu iwe joanu orikini ese ikini
Ako we re wipe
ni atetekose ni Oro tiwa
Oro siwa pelu Olorun
Olorun sini Oro re
Oro to n gbala to n wosan Oro Iye

Oro n la loruko re
Kabi o osi alade ogo
(Jesu)2*

Orobale mile titi.
Oro gbenu Orun fohunOro
.Oro sodi Oro
Oro sekaleOro
Oro je sulaya
Oro to ji oku dide
ikanni keje Oro
Oro imole
Oro iwo san
Oro igbala
Kiki Oro
Oro sekale oro
Oro mimo
Oro ogo
Oro n la
Oro Iye

Otade won fe gbope
Jesu de lowa gbope o
Ota durosokere
Lati gbomi lojumi
Imole tan o kunkun sa
Ota kigbe pe agbe ooo
Lemimimo bagbope
Oro no ye

Oro n la
Loruko re
Kabi o osi alade ogo (Jesu 2*)

Oro to n tunisile to Jani nide.
Oro to n gbani kuro ninu ogun esu.
Oro to n munileke to n  gbenileke to n munibori

Jesu ye oooo

Oro n layi
Loruko re oo
Kabi o osi o
Alade ogo
Imole ta o lepa oo
Ekun lafin Orun o
Oba alade Iye
Iye re ooo


Oro n la Oro n la
Oro n la Jesu- continue till fade.

Oro to n gbani la
Oro to n ji oku dide
Oro to n laju afoju
Oro to Faye eni sebu gbe
Ofohun re oku jidide
Ofohun re ojo ro
Ara San 
Ile mi titi

Ota de won Fe gbope
Jesu de lowa gbope oo
Ota durosokere
Lati gbomi lojumi
Imole tan okunkun sa
ota kigbe pe agbe ooo
Le mi mimo bagbope
Oro no ye

Oro mimo Oro Iye
Oro igbala Oro iwosan
Oro itusile Oro idan de
Oro imole Oro Ogo
Oro n la imole Oro
Oro mimo Oro mimo
Oro tin monu eda
Oro Oro Oro Jesu ni Oro

Listen,share, enjoy and Download below;
                         DOWNLOAD MP3

Post a Comment

1 Comments

Drop your Comment Below